Rosa de Carvalho Alvarenga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Rosa de Carvalho Alvarenga ni a tumọ si Dona Rosa de Cacheu ati Na Rosa ('Senhora Rosa') (1780s – d. lẹ̀yin ọdun 1857) jẹ oniṣowo oko ẹru ti ilẹ Euro-Afrika[1][2].

Itan Igbèsi Àye Rosa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Rosa jẹ ọmọbinrin Portuguese Manuel de Carvalho Alvarenga lati Cape Verde ati pe iya rẹ jẹ ilẹ́ Afrika, ọmọ iya gomina Francisco de Carvalho Alvarenga[3]. Rosa fẹ́ Joao Pereira Barreto (1772–1829) to si di iya Honorio Pereira Barreto (1813-1859) tosi di gomina ni ọdun 1830–1859. Rosa ṣe owo ẹru, cotton, irẹsi ati oyin, o tun ṣe agbatẹru owo larin ilẹ portuguese ati ilẹ Afrika. Rosa jẹ alagata óṣèlu larin ilẹ Portuguese ati ilẹ Afrika papa julọ ninu ija ogun ti ọdun 1840s. Ni gba kan ni ọdun 1850s, Rosa di ọkan ninu oko owo ni agbegbe naa[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Havik, Philip J (2016-01-10). "Rosa de Carvalho Alvarenga". Academia.edu. Retrieved 2023-08-26. 
  2. "Rosa de Carvalho Alvarenga (c. 1780 – c. 1865) - Biografias de Mulheres Africanas". Biografias de Mulheres Africanas (in Èdè Pọtogí). 2020-07-03. Retrieved 2023-08-26. 
  3. Havik, Philip J. Havikphilip J. (2011-01-01). "Carvalho Alvarenga, Rosa de". Oxford Reference. Retrieved 2023-08-26. 
  4. Brooks, G.E. (2010). Western Africa and Cabo Verde, 1790S-1830S: Symbiosis of Slave and Legitimate Trades. AuthorHouse. p. 192. ISBN 978-1-4520-8869-3. https://books.google.com.ng/books?id=yIm0ElCNK1gC&pg=PA192. Retrieved 2023-08-26.