Jump to content

Rose Francine Rogombé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rose Francine Rogombé
Fáìlì:Rose Francine Rogombé.png
President of Gabon
In office
10 June 2009 – 16 October 2009
Alákóso ÀgbàJean Eyeghé Ndong
Paul Biyoghé Mba
AsíwájúDidjob Divungi Di Ndinge (Acting)[1]
Arọ́pòAli Bongo Ondimba
President of the Senate of Gabon
In office
17 February 2009 – 27 February 2015
ÀàrẹOmar Bongo
Herself
Ali Bongo Ondimba
AsíwájúRené Radembino Coniquet
Arọ́pòLucie Milebou Aubusson
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Rose Francine Etomba

(1942-09-20)20 Oṣù Kẹ̀sán 1942
Lambaréné, French Equatorial Africa (now Gabon)
Aláìsí10 April 2015(2015-04-10) (ọmọ ọdún 72)
Paris, France
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDG
(Àwọn) olólùfẹ́Jacques Rogombé

Rose Francine Rogombé (née Etomba) (ọjọ́ ogún oṣù kẹsàn-án ọdún 1942 – ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù kẹrin ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Gabon politician àti adilémú fún ipò Ààrẹ láti oṣù kẹfà ọdún 2009 di oṣù kẹsàn-án ọdún 2009, lẹ́yìn ikú Ààrẹ Omar Bongo. Ó rọ́pò Ààrẹ nítorí pé òun ló jẹ́ Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ asofin nígbà tí Omar fi ayé sílẹ̀,[2] a yàn sí ipò Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ asofin ní oṣù kejì ọdún 2009.[3] Rose jẹ́ agbejọ́rò àti ọmọ ẹgbẹ́, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Gabonese Democratic Party (PDG).[4] Rogombé jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ láti di adarí orílẹ̀ ède Gabon. Lẹ́yìn ìgbà tí ìjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílẹ̀ ède Gabon wá sópin, ó padà sípò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ asofin Gabon.[5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Rulers.org – Gabon
  2. "Gabon's Senate speaker becomes interim head of state", AFP, 10 June 2009.
  3. Christian Walter Ngouah-Beaud, "Portrait: Rose Francine Rogombé, du prétoire au perchoir" Archived 18 February 2009 at the Wayback Machine., Gabonews, 17 February 2009 Àdàkọ:In lang.
  4. Magnowski, Daniel (16 May 2009). "Gabon's Bongo in Europe, "resting" from duties". Reuters. http://uk.reuters.com/article/latestCrisis/idUKLG268655. Retrieved 8 June 2009. 
  5. "Gabon: Rose Rogombé regagne son terreau du Sénat", Gaboneco, 20 October 2009 Àdàkọ:In lang.
  6. Skard, Torild (2014) "Rose Rogombé" in Women of power – half a century of female presidents and prime ministers worldwide, Bristol: Policy Press ISBN 978-1-4473-1578-0, pp. 313–4