Rose Moss

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Rose Rappoport Moss (tí wọ́n bí ní 1937) jẹ́ òǹkọ̀wé ti Orílẹ̀ èdè America, tí wọ́n bí ní South Africa.[1][2] Ó kó lọ sí ìlú America ní ọdún 1961.[3] Ó ti ṣe àgbéjáde ìwé ìtàn-àròsọ, ìtàn kékèèké, ọ̀rọ̀-fún orin àti àwọn ìtàn-àìròtẹ́lẹ̀.[4] Ní àfikún, ó fìgbà kan jẹ́ olùkọ́ ní Wellesley College.[5] Òun àti Barney Simon, pẹ̀lú Rose Zwi, jìjọ jé ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òǹkọ̀wé ti ilẹ̀ Johannesburg.[6] Wọ́n ti yan ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rẹ̀ fún ìtúpalẹ̀ èdè.[7]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]