Jump to content

Barney Simon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Barney Simon
Ọjọ́ ìbí(1932-04-13)13 Oṣù Kẹrin 1932
Ọjọ́ aláìsí30 June 1995 (aged 63)
Iṣẹ́Playwright, director
ÈdèEnglish
Ọmọ orílẹ̀-èdèSouth African
Notable worksWoza Albert!

Barney Simon (ọjó kẹtàlá oṣù Ìgbé ọdún 1932 – si ọgbọn ọjó oṣù okundu ọdún 1995)[1] kí a má ṣe dà á pọ mọ́ Jacaranda FM radio DJ Barney Simon. Barney Simon jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ South African àti olùdarí fíìmù. Ìlú Johannesburg ní SOuth Africa ni wọ́n bi sí, ibẹ̀ sì ni ó kú sí.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Simon ṣe àwárí ìfẹ́ rè fún iṣẹ́ tíátà lásìkò tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Joan LittlewoodLondon, ní ọdún 1950. Lẹ́yìn tó padà sí Johannesburg, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i òǹkọ̀wé fún ilé-iṣẹ́ ìpolówó-ọjà kan, lásìkò tó ń ṣịṣẹ́ olùdarí fún fíìmù. Ki o tó ṣí ọjà náà, o n ṣe eré ìtàgé nibi gbogbo ti ọ bá ti ni ore ọfẹ lati ṣe: in warehouses and shantytowns, storefronts and back yards, including Athol Fugard's The Blood Knot (1961). Simon spent a year (1969–70) in New York City, where he introduced South African plays to an American audience and edited the journal New American Review.

Àwọn ìwé àtẹ̀jáde rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àṣààyàn erẹ́-oníṣe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Phiri (1972)
  • Hey Listen (1973) is
  • People (1973)
  • People Too (1974)
  • Storytime (1975)
  • Cincinnati (1979)
  • Cold Stone Jug (1980)[3]
  • Call Me Woman (1980)
  • Marico Moonshine and Manpower (1981)
  • Woza Albert! (1981)
  • Black Dog-Inj Mayama (1984)
  • Born in the RSA (1985)[4]
  • Outers (1985)
  • Klaaglied vir Kous (1986)
  • Inyanga - about Women in Africa (1989)
  • Eden and Other Places (1989)
  • Score me the Ages (1989)
  • Starbrites (1990)
  • Singing The Times (1992)
  • Silent Movie (1993)
  • The Lion and the Lamb (1993)
  • The Suit (1994)
  1. Nadine Gordimer (3 July 1995). "Obituary: Barney Simon". The Independent. https://www.independent.co.uk/news/people/obituary-barney-simon-1589772.html. 
  2. Mary Benson (3 July 1995). "Obituary; Barney Simon: For freedom of the heart and mind". The Guardian: p. 12. 
  3. B. Simon; S. Gray; H. C. Bosman (1982), Cold Stone Jug, Cape Town: Human & Rousseau. ISBN 978-0-79811-309-0
  4. Barney Simon (1997), Born in the RSA: four workshopped plays, Johannesburg: Witwatersrand University Press. ISBN 978-1-86814-300-9