Roseline Òṣípìtàn
Roseline Òṣípìtàn |
---|
Oloorì Roseline Omolará Osípìtàn jẹ́ ọmọọba ilé Yorùbá, ó sí tún jẹ́ Oníṣòwò orílé èdè Nàìjíríà. Ọ tí jẹ Ààrẹ àti Aláàga rí fún ilé iṣé Independent Petroleum Marketers Association ti Egbé àwọn obìnrin, ó sí jẹ́ Olùdásílẹ̀ Ilé iṣé Royal Oil and Gas. Òun náà sini Yèyé Ọba fún ìlú Ìtòrì.
Ìtàn ìgbé Ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oloorì Roseline Osípìtàn jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Òndó ní orílé èdè Nàìjíríà. Osípìtàn sí ń ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Oníṣòwò àgbà fún ilé iṣé epo-rọ̀bì kàn ní orílé èdè Nàìjíríà, níbi tí ó tí jẹ́ ọkan lára àwọn Obìnrin Adarí.[1][2] Osípìtàn ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ àti Aláàga fún IPMAN tí Egbé àwọn obìnrin, èyí tí o dá gẹ́gẹ́ bí òdì Kejì fún Egbe IPMAN tí orílé èdè Nàìjíríà.[3] Ospitian jẹ́ ẹni tí ó dá ilé iṣé First Royal Oil and Gas sile.[4]Ó sí jẹ́ àyà fún Ọmọoba Bọ́lá Osípìtàn àti Yèyé Ọba tí ìlú Ìtòrì.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Roseline Osipitan shines on - The Nation". Latestnigeriannews.com. Retrieved 2018-12-09.
- ↑ "Omolara Osipitan puts best foot forward". Africanewshub.com. Archived from the original on 2023-04-05. Retrieved 2022-08-17.
- ↑ Audu, Adetutu (30 November 2014). "Roseline Osipitan shines on". The Nation Nigeria. Retrieved 9 December 2018.
- ↑ 4.0 4.1 "The Senator Ajibola and Princess Rose Osipitan Children’s nuptial people are dying to read on this blog + Groom’s Dad is a 4th term Senator and Bride’s mum an oil baroness …How Sweet Sensation joined them together". Asabeafrioka.com. Archived from the original on 2018-08-27. Retrieved 2022-08-17.
- Àwọn ènìyàn alààyè
- 20th-century Nigerian businesspeople
- 21st-century Nigerian businesspeople
- Nigerian women company founders
- Nigerian businesspeople in the oil industry
- Nigerian women business executives
- Nigerian princesses
- People from Ondo State
- African queen mothers
- Yoruba princesses
- Yoruba women in business
- 20th-century businesswomen
- 21st-century businesswomen
- Year of birth missing (living people)
- Yoruba queens