Rosie Stephenson-Goodknight

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Rosie Stephenson-Goodknight
Rosie Stephenson-Goodknight.jpg
Àwòrán Stephenson-Goodknight tí Wikimedia Foundation yà ní gbangba ní ọdún 2015
Ibùgbé Ìlú Nevada ní ìpínlẹ̀   California[1]
Orúkọ míràn Rosiestep
Iṣẹ́ alámójútó okùnòwò
Known for olótú Wikipedia
Children Sean
Relatives

David Albala (bàbá bàbá rẹ̀)

Paulina Lebl-Albala (ìyá ìyá rẹ̀)
Awards Èbùn kóríyá Wikipedia  (2016)

Rosie Stephenson-Goodknight, tí a tún mọ̀ sí  Rosiestep ní Wikipedia jẹ́ olótú Wikipedia ọmọ ìlú Amẹ́ríkà tí ó gbìyànjú láti ri wípé ojú opó ìmọ̀ ọ̀fẹ́ yìí jẹ́ oun tí takọ tabo á má a dásí tí ó sì ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò tí ó jẹ́ ki iye àwọn àyọkà nípa obìrín tó póṣùwọn pọ̀ síi. [2] Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àyọkà tí ó sì gba ẹ̀bún kóríyá Wikipedia ti ọdún 2016.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]