Roza Otunbayeva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Roza Otunbayeva
Роза Отунбаева
Roza Otunbayeva - World Economic Forum on Europe 2011.jpg
President of Kyrgyzstan
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
3 July 2010
Asíwájú Kurmanbek Bakiyev
Prime Minister of Kyrgyzstan
Acting
Lórí àga
7 April 2010 – 19 May 2010
Asíwájú Daniar Usenov
Arọ́pò Vacant
Minister of Foreign Affairs
Lórí àga
1992–1992
President Askar Akayev
Aṣàkóso Àgbà Tursunbek Chyngyshev
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Kẹjọ 23, 1950 (1950-08-23) (ọmọ ọdún 67)
Osh, Soviet Union (now Kyrgyzstan)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Social Democratic Party
Alma mater Lomonosov Moscow State University
Ẹ̀sìn Islam[1]

Roza Isakovna Otunbayeva (Àdàkọ:Lang-ky, Rọ́síà: Роза Исаковна Отунбаева; ojoibi August 23, 1950) ni Aare orile-ede Kyrgyzstan. Won bura re ni July 3, 2010, leyin to ti dipo bi olori igbadie leyin ijidide April 2010 to fa lilekuro Aare Kurmanbek Bakiyev lori aga. Otunbayeva je alakoso oro okere tele ati olori ipade ileasofin fun Egbe Toseluaraalu Awujo ile Kyrgyzstan.

Otunbayeva ni obinrin akoko ti yio je Aare orile-ede omo egbe CIS/SCO.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]