Rubén Aguirre
Ìrísí
Rubén Aguirre | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Rubén Aguirre Fuentes 15 Oṣù Kẹfà 1934 Saltillo, Coahuila, Mexico |
Aláìsí | 17 June 2016 Puerto Vallarta, Jalisco, Mexico[1] | (ọmọ ọdún 82)
Iṣẹ́ | Àdàkọ:Cslist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1967–2016 |
Notable work | Professor Jirafales in El Chavo del Ocho |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
Olólùfẹ́ | Consuelo de los Reyes (m. 1959) |
Àwọn ọmọ | 7[2] |
Signature | |
Rubén Aguirre Fuentes (Pípè: [ruˈβen aˈɣire ˈfwentes]; tí wọ́n bí ní 15 June 1934, tó sì ṣaláìsí ní 17 June 2016) fìgbà kan jẹ́ oṣèrékùnrin àti apanilẹ́rìn-ín ti ilẹ̀ Mexico.[3]Nígbà tó bẹ̀rẹ̀ sí í wá iṣẹ́ ṣe gẹ́gẹ́ bí òṣèré, wọ́n sọ fún un pé ní ẹsẹ̀ mẹ́fà 7 inches (2.01 m) ó ga jù.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Mexican actor Ruben Aguirre dies at 82". BBC News.
- ↑ Notice of death of Rubén Aguirre, globo.com; accessed 17 June 2016. Àdàkọ:In lang
- ↑ Aguirre, Rubén (2015) (in es). Después de Usted. Planeta Publishing Corporation. ISBN 9786070725180.