Jump to content

Ruth Kadiri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ruth Kadiri in the Nigerian film "First Class" in 2016
Ruth Kádírì
Ọjọ́ìbíọjọ́ Kẹrìlélógún oṣù Kẹta ọdun 1988
ìlú Benin
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́Mass communications,Yunifásítì ìlú Èkó
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásítì ìlú Èkó
Iṣẹ́òṣèré orí-ìtàgé

Ruth Kádírì jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùkọ fọ́rán àwòkà eré ìtàgé àti olùgbéré jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Ruth ní ọjọ́ Kẹrìlélógún oṣù Kẹta ọdun 1988 ní ìlú Benin tí ó jẹ́ olú-ìlú fún Ìpínlẹ̀ Ẹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí Ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti Yábàá, tí ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Business Administration, bákan náà ni ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde gboyè àkọ́kọ́ ní Yunifásítì ìlú Èkó nínú ìmọ̀ ìbá ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (Mass communications) .[1]

Àwọn Ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]