Rym Breidy
Rym Saidi Breidy [1] ريم بريدي | |
---|---|
Saidi on the May 2012 cover of Tunivisions | |
Ọjọ́ìbí | Rym Saidi 10 Oṣù Kẹfà 1986 Tunis, Tunisia |
Orílẹ̀-èdè | Tunisian |
Orúkọ míràn | Rym Saidi, Rim Saidi |
Iṣẹ́ | Model, Actress |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
Olólùfẹ́ | Wissam Breidy (m. 2017) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Rym Saidi Breidy (Lárúbáwá: ريم بريدي)(bíi ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà ọdún 1986) jẹ́ mọ́dẹ́lì àti òṣèré lórílẹ̀-èdè Tunisia.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Rym Breidy bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí mọ́dẹ́lì ní ọdún 2003 lẹ́hìn tí ó gbé igbá orókè níbi ìdíje Elite Model Look Tunisia. Ní ọdún 2006, ó gbé ipò kìíní níbi ìdíje MISSION FASHION[3]. Ní ọdún 2007, ó di mọ́dẹ́lì fún MP Models[4]. Ó ti si ṣé gẹ́gẹ́ bí mọ́dẹ́lì fún Profile models ní London,[5] Women Model Management ní Milan,[6] MP Management ní Paris, One.1 Management ní New York City,[7] Munich Models ní Germany,[8] MP Mega ní Miami.[9]. Ó gbajúmọ̀ ni Italy fún ipa Madre Natura[10][11] tí ó kó nínú eré Ciao Darwin. Ó jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ fún ilé iṣẹ́ Traveltodo láti ọdún 2013.[12][13][14][15]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kerìndínlọ́gún oṣù keje ọdún 2017, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Wissam Breidy.[16] Ó ti bí ọmọ bìnrin méjì.[17][18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Rym Saidi Breidy on Instagram: “Officially Mr & Mrs Breidy. Back to Beirut for the preparations of our big day. #first #September #2017 #love #always #win الحب دائما يفوز”". Instagram.
- ↑ "Rym Saidi - Portfolio - MP Management". Mpmegamiami.com.
- ↑ "Rencontre avec Rim Saidi la gagnante du concours Elite Tunisie et Mission Fashion Liban 2006". Babnet.net.
- ↑ "MP PARIS - RIM SAIDI". Mpparis.fr. Archived from the original on 2018-08-01. Retrieved 2016-08-25.
- ↑ "Rym . | Women | Beautiful model working in London modelling industry". Profile-models.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2016-08-25.
- ↑ "WOMEN DIRECT MILANO / WOMEN DIRECT MILANO - RYM". Womendirect.it. Archived from the original on 23 September 2016. Retrieved 25 August 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "ONE MANAGEMENT - RYM SAIDI". One.1management.com. Retrieved 2016-08-25.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Global, cDs. "RYM SAIDI represented by Munich Models. Direct division". Munich-models.de. Retrieved 2016-08-25.
- ↑ "MP MEGA MIAMI - Rym Saidi". Munich-models.de.
- ↑ "Chi è Madre Natura? Rym Saidi nella terza puntata". Blasting News.
- ↑ "Rym Saidi, la nuova Madre Natura di Ciao Darwin è la più sexy di tut...". Oggi.it. Retrieved 2016-08-25.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 16 December 2015. Retrieved 19 July 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "L'agence Traveltodo réprimende le mannequin Rim Saïdi - Destination Tunisie". Destinationtunisie.info. 5 October 2015.
- ↑ "Traveltodo remet en cause sa collaboration avec Rim Saïdi". Espacemanager.com.
- ↑ "Vidéo: Quand une célébrité tunisienne empêche ses amies de visiter la Tunisie - Réalités Online". Realites.com.tn. 4 October 2015.
- ↑ "Spécial Magazine - Wissam Breidy and Rym Saidi Said YES". Specialmagazine.co. Archived from the original on 15 May 2019. Retrieved 30 October 2018.
- ↑ [1] [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "وسام بريدي وريم السعيدي يرزقان بطفلتهما الثانية "آيا صوفيا" وهذه أول صورة لها". albawaba.com (in Arabic). 16 January 2020.
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages with citations using unsupported parameters
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from June 2024
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Articles with dead external links from October 2018
- CS1 maint: Unrecognized language
- Articles containing Arabic-language text