S'Nabou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
S'Nabou ní Le Monde illustré, oṣù keje ọdún 1892.

Alima S'Nabou (tí a bí ní ọdún 1880) jẹ́ atúmọ̀ èdè (tí ó wá láti ibi tí Nàìjíríà wà lónìí) tí ó tẹ́lèé arìnrìn-àjò Faransé kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Lieutenant Mizon.

Ìtàn rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Alima S'Nabou sínú ìdílé olóyè Konanki, nínú ìlú Igbobé, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Lokoja níbi tí odò Benue àti Niger ti pàdé. Ó gbó èdè Faransé, Gẹ̀ẹ́sì, àti àwọn èdè Niger míràn.[1] S'Nabou wà ní Assaba, nígbà tí ó pàdé Mizon[2] tí ìyá rẹ̀ sì sọ pé kí ó tẹ̀lé Mizon nínú ìrìn àjò rẹ̀ lọ sí Lokoja kí ó bà le rí bàbá rẹ̀, nítorí Mizon ń lọ sí Lokoja nígbà náà, S'Nabou jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá sí mọ́kànlá nígbà náà. Ní Lokodja, S'Nabou sọ fún bàbá àti ìyá bàbá rẹ̀ pé òun fẹ́ tẹ̀lé Mizon nínú ìrìn-àjò rẹ̀ lọ sí Yola, olú-ìlú of Adamawa.[3][4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. (in it) Bollettino della Società africana d'Italia. La Società.. 1892. https://books.google.com/books?id=P3tbAAAAIAAJ&q=S%27Nabou&pg=PA172. 
  2. "En Plein Soudan" (in fr). La Lecture: Magazine littéraire bi-mensuel 22. 1892. https://books.google.com/books?id=84kZAAAAYAAJ&q=S%27Nabou&pg=PA314. 
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :2
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :3
  5. Alis, Harry (1892). "Voyage dans l'Amadaoua par le Lieutenant de Vaisseau L. Mizon" (in fr). Le Tour du Monde 64: 225–288. https://books.google.com/books?id=xYXlAAAAMAAJ&q=S%27Nabou&pg=RA1-PA225. Retrieved 20 June 2021.