Sàbúrì Bíòbákú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sàbúrì Bíòbákú
ÌbíJune 16, 1918
Abẹ́òkúta
Aláìsí2001
Ará ìlẹ̀Ọmọ Nàìjíríà
Ẹ̀yàYoruba
PápáHistory
Ilé-ẹ̀kọ́University of Ibadan University of Lagos
Ibi ẹ̀kọ́Trinity College, Cambridge
Ó gbajúmọ̀ fúnYorùbá historiography
Religious stanceIslam

Sàbúrì Oladeni Bíòbákú (1918 - 2001) jẹ́ Ọ̀mọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Bíòbákú jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ̀n nínú ìmọ̀ Ìtàn Samuel Johnson nínú ìwádìí ọ̀rọ̀ -ìtàn Yorùbá.