Sányẹ̀rì
Ìrísí
Ìwé-alàyé[ìdá]
Olaniyi Afonja a.k.a SANYERI | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀wá 1974 Oyo State, Nigeria |
Ibùgbé | Ikeja |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actor,Comedian |
Olólùfẹ́ | Hawawu Omolara Afonja (m. 2013) |
Àwọn ọmọ | 2, Boluwatife Afonja, Olasunkanmi Afonja |
Ọláníyì Mikail Àfọ̀njá, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sányẹ̀rì jẹ́ Òṣèré orí-ìtàgé, adẹ́rínpòṣónú, Olùgbéré jáde ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.[1]
Ibẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Oláníyì Àfọ̀njá ní ìpìlẹ̀ Ọ̀yọ́, tí ó si jẹ́ akọ́bí ẹbí rẹ̀. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ St. Micheal ní Oke-Ìbò àti Ilé-ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Girama Durbar ní ìpínlẹ̀ [Ọ̀yọ́]] kan náà.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Dolapo, Amodeni (13 December 2013). "Comic actor, Sanyeri denies using wedding to raise funds". Ecomium Weekly. http://www.encomium.ng/comic-actor-sanyeri-denies-using-wedding-to-raise-funds/. Retrieved 11 February 2016.
- ↑ Bada, Gbenga (2018-11-08). "Sanyeri is the successful joker at 40". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-12-14.