Sìnáì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Map of the Sinai Peninsula with country borders shown.

Sinai tabi Peninsula Sinai; Lárúbáwá: سيناءsīnā'a; Hebrew סיני) je peninsula onigunmeta kan ni Egypt to je be 60,000 km2 (23,000 sq mi). O dubule si arin Omiokun Meditareani si ariwa, ati Omiokun Pupa si guusu, be sini ohun nikan ni apa ile Egypti to budo si Asia niyato si Africa. Lapapo mo oruko onibise re, awon ara Egypti tun pe ibe ni "Ile Fayrous" ("Land of Fayrouz"), toduro lori oro ede Egypti Ayejoun "Dumafkat", to ni itumo kanna. Peninsula na je pinpin si ile-gomina Egypti meji, o si ni olugbe bi egbegberun 1.3 awon eniyan.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]