Sẹ̀mítíìkì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Semitic

Semitiiki

Semitic ni àwon ènìyàn ka ju ti o si ye won jù síbè àwon èdè kan wa ti won kò mo rárá nipá sise arópò extant ati extinet kan. Semitic se ipate adoofa lorisiirisi. Nípa ìsàkóso ti ìbílè won sùgbón dosini kan àbò lo wà lábé ìsàkóso àwon Arabiki, sùgbón àwon kan rò wípé ko ba ojú mu lati se be. Àwon Oludari kan gba pe Semitic a le ri oruko won ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwo Òòrun àti Gusu lábé ipin eka ìdílé kan sùgbón aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pèlú èka ìdílé Gúsù. Arákùnrin tí Orúko rè ń je Hetzron (1972: 15-16)5 se àríyànjiyàn lórí ipò

(1) Eka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jé ayé òlàjú tó ti kojá lo ti àwon Assyrians àti Babylonians nígbà to si je pé Akkadian wà ní lílò fún nnkan bi Odún meji milinionu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwò Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúsù àríwá si èka. Ti àwon Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àsìkò ìgbà ayé àtijó ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wón ń so lati nnkan bí Centiuri mewa BC. Séyìn. nnkan bì Centiuri méfà séyìn àwon kirisiteni Aramaic nìkan ní ó jé èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilè je pé àwon èdè tí á ń so ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwò Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwon Olùso èdè ní Assyrian (200).


2. Eka arìngbùngbùn Gusu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí paré legbe èdè ìlà Òòrun gégé bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew. Àwon phonecian, ni tòótó won ń sòrò nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwon keteji (Carthage) níbi tí á tí mo hàn-án bí puniki. Èdè ìgbàlódé ti àwon Hébérù ń so ni Isrealis lo se àtúnse re (4, 510). Èdè tí àwon Ras Shamra àti Uguritic ń so kàyéfì lo jé. Èdè to ti pé tí àwon Quran ń lò láti Centiuri kerin AD, lo wà sùgbón nígbà tó yá wón padà sí tí Centiuri karun BC; sùgbón síbè wón ko so mó. Loni Orísìírìsí ìpínlè Arábìkì tí wón ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwò Afíríkà. Ní Áfíríkà àwon èdè tó hàn gbegedé won si pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti won ń so ní Mauritania àti díè lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), won ń so díè ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wón ń so ní Àríwá Sudan sùgbón pèlú àwon Olùso èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wón ń so Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) sùgbón wón ń so èdè yìí díè ní Libya àti Egypt. Ó dá hàn yàtò sí èdá òrò aláwomo èdè oni ti Arabiki sùgbón èdè Arabiki ní a ń lò fún èkó Ìsàkóso àti Ìgbòòrò Ìbánisòrò bakan náà a ń lo gégé bi èdè kejì ó si jé èdè ìpìnlè àkóko fún èdè Arábìkì. Ìyàtò èdá Ìgbédègbéyò wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkókó Ferguson (1959) Maltese (330) won ń sòrò nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlè èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki sùgbón tí ó tí tàn ka láàrín àwon Italiàni.


(3) Sémítìkì to wa ní Gusu kún fún àwon Arabiki Gusu àti Ethic Semitic Sùgbón àwon ti télè kún fún Orísìírísí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mò láti ìwò Òòrùn Gusu Arábìkì àkosílè rè tí wà láti Centiuri méjo BC pèlú Arábìkì ti Gusu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Sùgbón ki i se gbogbo àwon Òmòwé to gboye nínú koko ise kan lo fara mò. Ethic-Semitic kún fún àwon ará Àríwá Eghiopic àti èka òrò aláwòmó àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní èka Gusu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín. Amharic (20, 000) èdè Ethopia je tí gbogbo gbo ó wà lára ti télè gégé bi Harari (26), O jé eni ti ahón rè fanimóra tí ó si je tí ìbìlè si gbogbo ìlú Harari gbogbo àwon egbé atòdefimò gbárajo pèlú àwon ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gégé bí Soddo (104) yàtò si tí àringbùngbùn tí ìwò Òòrùn pèlú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wón je sòròsòrò (1,856) Orísìírírìsí nnkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a si se àpínsowoó rè si egbé èyí ti o wa láàrín. Ó se pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á si fi hàn gégé bi èdè kan.