Jump to content

Saad Al-Salim Al-Sabah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saad Al-Abdullah Al-Salem Al-Sabah
Sheikh Saad in 1991
Reign 15–24 January 2006
Predecessor Jaber Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah
Successor Sabah IV Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah
Spouse Sheikha Latifa bint Fahad Al-Sabah
House House of Al Sabah
Father Sheikh Abdullah Al-Salim Al-Sabah
Mother Jameela (an Ethiopian)[1]
Born 1930
Kuwait
Died 13 May 2008(2008-05-13) (ọmọ ọdún 77–78)
Kuwait
Religion Islam

Sheikh Saad Al-Abdullah Al-Salim Al-Sabah, KCMG (Hon) (Lárúbáwá: سعد العبد الله السالم الصباحSaʿd al-ʿAbd Allāh as-Sālim as-Sabāh) (1930 – 13 May 2008) ló jẹ́ Ẹ́mírì ilẹ̀ Kùwéìtì àti Aláṣe Ológun ilẹ̀ Kùwéìtì fún ìgbà ṣókí ọjọ́ mẹ́sàn (láti 15 dé 24 January 2006), nígbà tó rọ́pò Sheikh Jaber. Sheikh Saad jẹ́ ọ̀gá aláṣe ní ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Kùwéìtì, ó tún jẹ́ alákòóo Ilé-iṣẹ́ Àkóso Ọ̀rọ̀ Abẹ́lé títí di February 16 1978.since 1964.[2]


  1. "LIFE". 17 September 1965. 
  2. [1] Nine Ministers headed the Interior Ministry since Kuwait's independence