Saint Martin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Saint Martin
Orúkọ àbínibí: Sint Maarten (Duki)
Saint-Martin (Faransé)

Sobriquet: The Friendly Island
Saint martin map.PNG
Jẹ́ọ́gráfì
Ibùdó Caribbean Sea
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn 18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.05°W / 18.067; -63.05Àwọn Akóìjánupọ̀: 18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.05°W / 18.067; -63.05
Àgbájọ erékùṣù Leeward Islands, Lesser Antilles
Ààlà 87 km2 (34 sq mi)
Ibí tógajùlọ 414 m (1,360 ft)
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ Pic Paradis
Orílẹ̀-èdè
Kingdom of the Netherlands
Constituent country  Netherlands Antilles
Island territory  Sint Maarten
Ìlú tótóbijùlọ Philipsburg (pop. 1,338)
France
Overseas collectivity  Saint Martin
Ìlú tótóbijùlọ Marigot (5,700)
Demographics
Ìkún 74,852 (as of January 1, 2007)
Ìsúnmọ́ra ìkún 860

Saint Martin (Faranse: Saint-Martin; Duki: Sint Maarten) je erekusu amooru ni ariwailaorun Karibeani, bi 300 km (186 miles) ilaorun orile-ede Puerto Rico. Erekusu yi to je 87 km2 je pipin ni 60/40 larin Fransi (53 km2)[1] ati Netherlands Antilles (34 km2)[2]; ohun ni erekusu to kerejulo ti awon eniyan n gbe si ninu okun ti o je pipin larin awon orile-ede meji, eyi je be lati odun 1648.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]