Samke Makhoba
Ìrísí
Samkelisiwe Makhoba | |
---|---|
Samke Makhoba | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kẹfà 1989 Umlazi,KwaZulu-Natal,South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Ẹ̀kọ́ | University of the Western Cape University of Witwatersrand |
Iṣẹ́ | actress |
Employer | MTV Shuga |
Samkelisiwe "Samke" Makhoba (tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n ọdún 1989) jẹ́ òṣèré Gusu Afirika tí ó kópa nínú eré Shuga èyí tí MTV gbé kalẹ̀.[1]
Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Makhoba sí ìlú Umlazi ní ọdún 1989. Ó kọ́kọ́ yàn láti kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Science ní Ilé- ẹ̀kọ́ gíga ti University of Western Cape ṣùgbọ́n ó yípadà láti kẹ́kọ̀ọ́ Fiimu & Tẹlifísíọ̀nù ní Ilé- ẹ̀kọ́ gíga ti University of Witwatersrand[2]
Awọ̀n ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Meet the cast of MTV Shuga Down South". ZAlebs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-02-22. Retrieved 2019-02-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Samke Makhoba | TVSA". www.tvsa.co.za. Archived from the original on 2019-02-23. Retrieved 2019-02-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)