Jump to content

Samuel L. Jackson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Samuel L. Jackson
Jackson ní ọdún 2022
Ọjọ́ìbíSamuel Leroy Jackson
21 Oṣù Kejìlá 1948 (1948-12-21) (ọmọ ọdún 76)
Washington, D.C., U.S.
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • United States
  • Gabon
Ẹ̀kọ́Morehouse College (BA)
Iṣẹ́
  • Actor
  • producer
Ìgbà iṣẹ́1972–present
WorksFull list
Olólùfẹ́
Àwọn ọmọ1
AwardsFull list

Samuel Leroy Jackson (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1948) jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè actor Amerika. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìran rẹ̀ a, àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré ti pa iye owó tí ó lé ní bílíọ́nù mẹ́tàdínlógún dọ́là ($27 billion), èyí mú kí ó jẹ́ òṣèré kejì tí àwọn eré rẹ̀ ti pa owó jù.[lower-alpha 1]. Ní ọdún 2022, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Honorary Award.[4][5][6]

Jackson bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òṣèré perewu ní ọdún 1980 nígbà tí ó ṣeré nínú Mother Courage and her ChildrenThe Public Theatre. Láàrin ọdún 1981 sí ọdún 1983, ó ṣeré A Soldier's Play off-Broadway. Ó tún ṣeré nínú fíìmù The Piano Lesson ní ọdún 1987 ní Yale Repertory Theatre. Ó kópa Martin Luther King Jr. nínú fíìmù The Mountaintop (2011).[7]

Àwọn eré tí Jackson kọ́kọ́ ṣe ni Coming to America (1988), Juice (1992), True Romance (1993), Menace II Society (1993), àti Fresh (1994).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Box Office Mojo – People Index". Box Office Mojo. Archived from the original on June 27, 2019. Retrieved October 17, 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Powers, Lindsay (October 27, 2011). "Samuel L. Jackson Is Highest-Grossing Actor of All Time". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/news/samuel-l-jackson-highest-grossing-actor-guinness-book-world-records-254155/. 
  3. "Samuel L. Jackson Movie Box Office Results". Box Office Mojo. Retrieved August 31, 2019. 
  4. Ferme, Antonio (2021-06-24). "Governors Awards: Samuel L. Jackson, Danny Glover, Elaine May and Liv Ullmann Set for Honorary Oscars". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-24. 
  5. "'This is going to be cherished': Samuel L Jackson and Elaine May receive honorary Oscars". TheGuardian.com. March 26, 2022. 
  6. Ables, Kelsey (26 March 2022). "Samuel L. Jackson accepts honorary Oscar in emotional ceremony". The Washington Post. https://www.washingtonpost.com/arts-entertainment/2022/03/26/samuel-l-jackson-oscar/. 
  7. "The Mountaintop, with Samuel L. Jackson and Angela Bassett, Extends Broadway Run". Playbill. Retrieved May 3, 2023. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found