Samuel Peter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Samuel Okon Peter
SamPeter.png
Statistics
Real nameSamuel Okon Peter
Nickname(s)The Nigerian Nightmare
Rated atHeavyweight
Height6 ft 1 in (1.85 m)
NationalityNigerian
Birth dateOṣù Kẹ̀sán 5, 1980 (1980-09-05) (ọmọ ọdún 39)
Birth placeNàìjíríà Akwa Ibom, Nigeria
StanceOrthodox
Boxing record
Total fights36
Wins33
Wins by KO26
Losses3
Draws0
No contests0

Samuel Okon Peter tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 1980 (September 5, 1980 ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà), tí orúkọ ni ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ "The Nigerian Nightmare," jẹ́ eléré ìdárayá ajẹ̀ṣẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríàtí ó jẹ́ ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àti olùborí ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àgbáyé WBC nígbà kan rí.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]