Sandra Prinsloo
Appearance
Sandra Prinsloo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Sandra Prinsloo 15 Oṣù Kẹ̀sán 1947 South Africa |
Ẹ̀kọ́ | University of Pretoria |
Iṣẹ́ | Actress |
Sandra Prinsloo (bíi ni ọjọ́ kẹẹ̀dúgún oṣù kẹsàn-án ọdún 1947) tí àwọn èèyàn tún má ń pè ní Sandra Prinzlow je òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá Kate Thompson tí ó kó nínú eré The gods must be crazy ni ọdún 1980.
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Prinsloo sọ wí pé òun kò lérò pé òun má jẹ́ òṣèré.[1] Iṣẹ́ oníjó ni ó ń ṣe tẹ́lẹ̀. Prinsloo gboyè láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Pretoria nínú ìmò dírámà.[2]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Gods Must Be Crazy,
- Target of an Assassin (1979),
- Quest for Love (1988)
- Die Prins van Pretoria (1992)
- Soweto Green (1995)
- Paw Paw Vir My Darling (2015),
- Twee Grade van Moord (2016).[3]
Tẹlẹfísọ̀nù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Egoli: Place of Gold[4]
- RaakPraat met Sandra[5][6]
- Sandra Op 'n Drafstap[7]
- Erfsondes (2012)
- Hartland (2011)
- Known Gods (2005)
- Saints, Sinners, and Settlers (1999)
- Konings (1991)
Eré orí ìtàgé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Miss Julie[8][9][10]
- 21 Icons[11]
- The Sewing Machine
- Oskar en die Pienk Tannie
- Janneman
- Nag, Ma (Night Mother)
- Liefde, Anna
- Jani[12]
Àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó gbà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2013, Prinsloo gba àmì ẹ̀yẹ tí ACT Lifetime Achievement Award fun ere ori itage[13]. Ní ọdún 2014, ó gbà ẹ̀bùn Order of Ikhamanga láti ọ̀dọ̀ ìjọba South Áfríkà fún àwọn ìṣe ribiti tí ó tí ṣe.[14][15] Ní ọdún 2018, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Lifetime Achievement Awards láti ọ̀dọ̀ Naledi Theatre Awards.[16]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Behind the Icon - Leading Lady: Sandra Prinsloo". News 24. 21 December 2014. Retrieved 6 June 2015.
- ↑ http://www.whoswhosa.co.za/sandra-prinsloo-5555 Archived 2011-09-01 at the Wayback Machine. Sandra Prinsloo Retrieved 29 December 2012
- ↑ Sandra Prinsloo. Internet Movie Database (IMDB). Retrieved 31 May 2015.
- ↑ [1] "Breaking: Sandra Prinsloo back in Egoli." TV with Thinus: News & Analysis on South Africa Television, 15 January 2010. Retrieved 1 September 2014.
- ↑ [2] "RaakPraat met Sandra - New on SABC2." Media Update, 13 November 2007. Retrieved 1 September 2014.
- ↑ [3] "RaakPraat met Sandra." TVSA: The South African TV Authority. Retrieved 1 September 2014.
- ↑ "The Prinsloo Phenomenon". Tonight (South Africa). 18 December 2012. Retrieved 31 May 2015.
- ↑ "Walkout over Black-White Love Scene". Courier-Mail (Australia). 8 March 1985. Retrieved 2 September 2014 from Lexis-Nexis database.
- ↑ [4] O'Brien, Kerry. "The 7:30 Report: Kani explores a post-apartheid world on stage." Australian Broadcasting Corporation, 11 May 2005. Retrieved 1 September 2014.
- ↑ Smith, Janet. "Kani's King Lear moment". The Star (Johannesburg). 13 February 2013. Retrieved 2 June 2015.
- ↑ "About the Project". 21 Icons. Retrieved 6 June 2015.
- ↑ Eenmanstuk oor Jani Allan se lewe Beeld. 23 July 2015
- ↑ "Celebrating artists who touch our lives". Tonight (South Africa). 19 November 2013. Retrieved 2 June 2015.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 24 September 2015. Retrieved 1 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) Diphoko, Montlenyane. "Zuma bestows 53 luminaries with National Orders." SABC News, 27 April 2014. Retrieved 1 September 2014. - ↑ [5] Archived 2014-09-03 at the Wayback Machine. "Zuma presents National Orders in Pretoria." The Citizen, 28 April 2014. Retrieved 1 September 2014.
- ↑ "Complete list of winners in 2018 Naledi Theatre Awards" Archived 2020-10-17 at the Wayback Machine.. Artsvark, 19 June 2018.