Satyendra Nath Bose
Satyendra Nath Bose সত্যেন্দ্র নাথ বসু | |
---|---|
Satyendra Nath Bose in 1925 | |
Ìbí | Calcutta, British India (now Kolkata) | 1 Oṣù Kínní 1894
Aláìsí | 4 February 1974 Calcutta, India (now Kolkata) | (ọmọ ọdún 80)
Ibùgbé | India |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Indian |
Pápá | Physics and Mathematics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Dhaka University of Calcutta |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Calcutta |
Ó gbajúmọ̀ fún | Bose–Einstein condensate Bose–Einstein statistics Bose gas |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Padma Vibhushan Fellow of the Royal Society[1] |
Religious stance | Hinduism |
Satyendra Nath Bose FRS[1](Bẹ̀ngálì: সত্যেন্দ্র নাথ বসু Shottendronath Boshū, Àdàkọ:IPA-bn;1 January 1894 – 4 February 1974) je was an Indian asefisiksi ara India to imo otooto ni fisiksi onimathimatiki. Won bi ni Kolkata, to je kiko nigbana bi Kalkutta. O gbajumo fun ise re lori isiseero oniyebintin ni ibere orundun 1920, nibi to ti pese ipilese fun statistiki Bose-Einstein ati arojinle Bose–Einstein condensate. Bose to je Ẹlẹgbẹ́ ni Royal Society, o gba ebun keji togajulo ni India fun araalu, Padma Vibhushan ni 1954 lowo Ijoba ile India.[2][3][4].
Awon eka awon eruku alapilese ti a mo bi bósónì je siso loruko fun[5][6] latowo Paul Dirac.[7]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ìtokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Àdàkọ:Cite doi
- ↑ Wali 2009, p. xv, xxxiv (Foreword).
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedBiography
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedSMahanti
- ↑ Subramanian, Samanth. "For the Indian Father of the ‘God Particle,’ a Long Journey from Dhaka". New York Times. http://india.blogs.nytimes.com/2012/07/06/the-man-behind-boson/. Retrieved July 7, 2012.
- ↑ Àdàkọ:OEtymD
- ↑ Notes on Dirac's lecture Developments in Atomic Theory at Le Palais de la Découverte, 6 December 1945, UKNATARCHI Dirac Papers BW83/2/257889. See note 64 to p. 331 in The Strangest Man by Graham Farmelo.