Sei Shōnagon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sei Shōnagon

Sei Shōnagon tí wọ́n bí ní ọdún 966, tí ó sìn kú ní ọdún 1025 (966 - 1025) jẹ́ oǹkọ̀wé àti akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Japan.