Jump to content

Sellapan Ramanathan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Indian name

S. R. Nathan
செல்லப்பன் ராமநாதன்
6th President of Singapore
In office
1 September 1999 – 31 August 2011
Alákóso ÀgbàGoh Chok Tong
Lee Hsien Loong
AsíwájúOng Teng Cheong
Arọ́pòTony Tan Keng Yam
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Keje 1924 (1924-07-03) (ọmọ ọdún 99)
Singapore
Ọmọorílẹ̀-èdèSingaporean
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
(Àwọn) olólùfẹ́Urmila Umi Nandey
Alma materUniversity of Malaya
ProfessionCivil servant

Sellapan Ramanathan[1] (Àdàkọ:Indic; ojoibi 3 July 1924) je oloselu are Singapore to je Aare ile Singapore kefa. O gbajumo bi S. R. Nathan, o koko je biburafun ni September 1, 1999. Ni 1999 ati 2005, o je didiboyan bi Aare lisi alatako. Ni 2009, o koja Benjamin Sheares lati Aare ile Singapore to pejulo lori ipo. Igba re pari ni August 31, 2011.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Yap, Sonny; Lim, Richard; Leong, Weng Kam (2009). Men In White - The Untold Story of Singapore's Ruling Political Party, p.145. Singapore Press Holdings Ltd., Singapore, ISBN 9789814266246