Separate (Orin)
"Separate" | ||||
---|---|---|---|---|
Single by Amanda Black | ||||
from the album Amazulu | ||||
Released | Oṣù Kọkànlá 7, 2016 | |||
Recorded | 2016 | |||
Genre | ||||
Length | Àdàkọ:Duration | |||
Label | Ambitiouz | |||
Songwriter(s) | Jabulani Hadebe | |||
Producer(s) |
| |||
Amanda Black singles chronology | ||||
|
"Separate" jẹ́ orin láti ọwọ́ olórin orílẹ̀-èdè South Africa ìyẹn Amanda Black, èyí tí ó gbé jáde gẹ́gẹ́ bíi orin àdàkọ rẹ̀ kejì léyìn tí ó ṣàgbéjáde àwò-orin àkọ́kọ́ rẹ̀, ìyẹn Amazulu. Wọ́n fọn ká sí oríṣiríṣi abala rédíò káàkiri ilẹ̀ South Africa ní ọdún 2016. Lẹ́yìn tí wọ́n gbé orin yìí jáde, ó bọ́ sí ipò kìíní lórí Metro FM. Ó bọ́ sí ipò kìíní ní orí àtẹ South African iTunes R&B.Sjava tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin Ambitiouz Entertainment ló kọ orin "Separate" sílẹ̀, Christer ló sì ṣiṣẹ́ olùdarí orin náà.
Àhunpọ̀ orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]"Separate" jẹ́ orin tó lọ wọ́rọ́wọ́, pẹ̀lú dùrù àti ọ̀pọ̀ ohùn. Sjava ló kọ́kọ́ kọ orin yìí kalẹ̀, tí Saudi (ọ̀kan lára àwọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ rẹ̀) sì dá sí orin náà. Ó jẹ́ orin tó múni lọ́kà gidi gan-an.
Ìgbóríyìn fún
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orin náà "Separate" gba àmì-ẹ̀yẹ Best R&B Single ní Metro FM Music Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀dógún irú ẹ̀.
Ọdún | Ayẹyẹ ìgbàmì ẹ̀yẹ | Àpèjúwe àmì-ẹ̀yẹ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2017 | Metro FM Music Awards | Best R&B Single | Gbàá | [1] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Reporter, Citizen. "Amanda Black gets her first award and Twitter goes crazy". citizen.co.za. Retrieved 15 September 2017.