Sergei Sidorsky
Ìrísí
Sergei Sidorsky Сяргей Сідорскі Сергей Сидорский | |
---|---|
Prime Minister of Belarus | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 July 2003 Acting until 19 December 2003 | |
Ààrẹ | Alexander Lukashenko |
Deputy | Vladimir Semashko |
Asíwájú | Henadz Navitski |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹta 1954 Homiel, Soviet Union (now Belarus) |
Sergei Sergeevich Sidorsky[1] (Bẹ̀l. Сяргей Сідорскі, Àdàkọ:IPA-be, Siarhiei Sidorski Rọ́síà: Сергей Сидорский) (ojoibi March 13, 1954 in Homiel, BSSR, Soviet Union) ni Alakoso Agba ile Belarus. O je yiyan bi Adipo Alakoso Agba ni July 10, 2003 lati ropo Gennady Novitsky ti o je lile kuro, o je mimudaju gege bi Alakoso Agba gangan ni December 19, 2003.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "PRIME MINISTER OF THE REPUBLIC OF BELARUS". Government of Belarus. Archived from the original on 3 March 2010. Retrieved 27 December 2009.