Seswaa
Ìrísí
Seswaa (gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe máa ń pè é ní àríwá orílẹ-èdè Botswana) tàbí loswao (gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe máa ń pè é ní gúúsù àti ìlà oòrùn orílẹ-èdè Gúúsù Áfíríkà) jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ tí wọ́n fi ẹran sè ní Botswana, tí a fi ẹran màálù tàbí ẹran ewúrẹ́ sè. A máa ń sè é nípa lílo àgékù ẹran gẹ́gẹ́ bíi ẹsẹ̀, ọrùn àti ẹ̀yìn. Ayẹyẹ bíi òkú àgbà, ìgbéyàwó, ọdún orílẹ-èdè la ti sábà máa ń bá oúnjẹ yìí.[1] A máa ń bọ eran náà pẹ̀lú iyọ̀ lásán,[2] a sì máa gun tó bá ti rọ̀.[3][4] Wọ́n sábà máa ń fi jẹ ẹ̀kọ, setampa (samp, àgbàdo lílọ̀) tàbí mabele (sorghum).[4][5][6]
Tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Firestone, M.D.; Karlin, A. (2010). Botswana & Namibia. Lonely Planet. p. 70. ISBN 9781741049220. https://archive.org/details/isbn_9781741049220. Retrieved 2015-02-22.
- ↑ Denbow, James Raymond; Thebe, Phenyo C.; Thebe, Phenyo C. (2006). Culture and Customs of Botswana. Bloomsbury Academic. ISBN 9780313331787. https://books.google.com/books?id=8ycoVZ-DfrYC&q=%22seswaa%22+salty&pg=PA112.
- ↑ Edelstein, Sari (April 2010). Food, Cuisine, and Cultural Competency for Culinary, Hospitality, and .... Jones & Bartlett Publishers. ISBN 9781449618117. https://books.google.com/books?id=NQoWQTVcpVIC&q=%22seswaa%22&pg=PA353.
- ↑ 4.0 4.1 "Seswaa recipe from Botswana". The Guardian. October 29, 2012. Retrieved January 12, 2017.
- ↑ Main, Michael; Smart!, Culture (13 October 2010). Botswana - Culture Smart!. Kuperard. ISBN 9781857335934. https://books.google.com/books?id=2rgBr_tmm1kC&q=%22seswaa%22&pg=PT118.
- ↑ Plessis, Heather Du (2000). Tourism Destinations Southern Africa. Juta and Company. ISBN 9780702152726. https://books.google.com/books?id=NCWM_ht3-KcC&q=%22seswaa%22&pg=PA203.