Ẹ̀kọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí wọ́n ṣẹ̀dá láti inú àgbàdo.

Eko Gbigbona ni mo mu laaro yi. Bayi ni mo se poo...

  1. Re agbado (corn) si inu omi tutu fun ojo meta.
  2. Lo o ni ero titi ti yo fi kun na.
  3. Jo pelu ase ki fi kun na sii.
  4. Bu die sinu ife (cup) tabi abo(dish)
  5. Bu omi hiho sii titi yo fi ki bi o se fe.
  6. O le bu suga tabi miliki si ki o si mu.