Sheril Angachi
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Sheril Angachi Andiba | ||
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kínní 2000 | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Gaspo Youth | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Gaspo Youth | |||
National team | |||
20 | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Sheril Angachi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọjọ akọkọ, óṣu january ni ọdun 2000. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun Gaspo Youth FC[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sheril kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ́ afirica to waye ni ọdun 2018[4].