Siatta Scott Johnson
Ìrísí
Siatta Scott Johnson سياتا سكوت جونسون | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Siatta Scott Johnson 1974 Buchanan, Liberia |
Orílẹ̀-èdè | Liberian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Liberia |
Iṣẹ́ | Director, producer, broadcast journalist, reporter, presenter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Siatta Scott Johnson (tí wọ́n bí ní Ọdún 1974) jẹ́ olùdarí àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Làìbéríà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré aláṣeyọrí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Iron Ladies of Liberia.[2] Yàtò sí ṣíṣe olùdarí eré, ó tún maá n gbé ìròyìn, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Omuahtee Africa Media.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "ists". Archived from the original on 2021-10-22. Retrieved 2020-11-28.
- ↑ "rain". Archived from the original on 2021-10-22. Retrieved 2020-11-28.
- ↑ in[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Àwọn ìtakùn Ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- New Strategies for Peace ahead of Elections in Liberia
- From 'Big Jues' To 'Tay-Tay Water,' A Quick Guide To Liberian English
- FEJAL Trains Female Journalists to Report on Electoral Reforms Archived 2020-10-14 at the Wayback Machine.
- 25 Female Journalists Trained in digital security Archived 2021-10-22 at the Wayback Machine.