Sikiru Adesina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Sikiru Adesina (1971 - February 8, 2016), tí òpòlopò mò sí Arakangudu, jé omo orile ede Nàìjíríà osere fiimu Yoruba, ati director.[1]. Oun ti o mu je gbajumo ni ipa ti o ma nsaba ko ninu ere, ipa bi babalawo, adigunjale ati oloogun.[2].Ni February 8, 2016, o salaisi ni ibugbe re ni Kaduna, Northern Nigeria.[3][4]

Àwon fiimu tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Temi Ni, Tie Ko
 • Agbede Ogun
 • Idunnu Mi
 • Ilu Gangan
 • Ogbologbo
 • Iya Oju Ogun
 • Ere Agbere
 • Agbede Ogun
 • Agba Osugbo
 • Aje Olokun
 • Iya Oko Bournvita
 • Igba Owuro
 • Ayaba Oosa
 • Ajana oro
 • Fijabi
 • Oju Odaran Re

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]