Simi Johnson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Simisola Olayemi Onibuwe Johnson (1929 – 2000) jé Dókítá Eyín àti ajafeto okunrin àti obínrin, ó sì tún jé Minisita fún idagbasoke awujo àti àsà.[1] O jé alaga teleri tí Allied Bank àti èka National Council of Women Societies ti Èkó. Johnson àti Grace Goubadia di Dókítá eyín ní 1957, èyí mú kí àwon méjèjì jé obinrin àkókó tí o di Dókítá èyin ní Nàìjíríà.

Ayé rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Johnson sínú idile Alfred Latunde àti Harriet Susan Johnson ní Island ìpinlè Èkó. Òun ni abikenyin àwon òbí rè. Baba rè jé agbejoro àti adari àkókó ti National Bank ti Nàìjíríà ní odun 1933. Johnson lo ilé-ìwé CMS Girl's School ní Eko. Ní àárín odun 1954 sí odun 1957, o lo kàwé ní ilé-ìwé Sunderland Technical College àti Yunifásitì ti Durham ki o to di Dokita èyin. [2] Johnson gba àmì-èye nínú isé abe èyin.

Ní orílè-èdè Nàìjirià, o sisé pèlú ijoba ní èka eto ilera.[2] Johnson bèrè isé pèlú ní 14 July 1958 ìjoba gégé bi alabe eyín, nibi tí o ti sisé ni General Hospital ti Eko láti odub 1958 si 1960s.

Jíjà fún ètó Obinrin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Johnson wà lara àwon tó bèrè women's right advocates.[2] Nígbà isejoba Shagari, Johnson di minisita fún idagbasoke awujo.

Ikú rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Simisola di ologbe ní odun 2000 ni omo odun aadorin.[3]

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Abati, R. (2004). The Whole Truth: Selected Editorials of the Guardian (1983-2003). Guardian Newspapers Limited. ISBN 978-978-2030-63-4. https://books.google.com/books?id=jBZzAAAAMAAJ. Retrieved 2022-05-29. 
  2. 2.0 2.1 2.2 "Simi Johnson". Wikipedia. 2016-08-07. Retrieved 2022-05-29.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Wikipedia 2016" defined multiple times with different content
  3. "Simi Johnson's biography, net worth, fact, career, awards and life story". ZGR.net. 2020-08-23. Retrieved 2022-05-29.