Jump to content

Simoné Nortmann

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Simoné Nortmann
Nortmann at the Fiestas in February 2018
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kàrún 1990 (1990-05-18) (ọmọ ọdún 34)
Pretoria, South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Iléẹ̀kọ́ gígaStellenbosch University
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2013–present
Olólùfẹ́
Andries Levi Pretorius (m. 2019)
AwardsTallgrass International Film Festival (2017)
Huisgenoot Tempo Awards (2017)
Websitesimonenortmann.com

Simoné Pretorius (bíi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1990) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Irma Humpel tí ó kó nínú eré Vir die voëls.[1] [2]Ó tún gbajúmọ̀ fún ipá Jony tí ó kó nínú eré Hotel, èyí sì jẹ ki o gba àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ South African Film and Television Award ni ọdún 2018. Eré tí ó fi kọ́kọ́ di gbajúmọ̀ ni 7de Laan(2013-2015) níbi tí ó tí kó ipa Nadia, èyí sì jẹ kò gbà ẹ̀bùn òṣèré tuntun tó dára jù lọ ní ọdún 2014 láti ọ̀dọ̀ Royalty Soapie Awards.[3][4]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1990 ni ìlú Pretoria ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Àwọn òbí rẹ jẹ ajagun fún orílè-èdè South Áfríkà[5]. Ó gboyè nínú eré ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Stellenbosch University ni ọdún 2012.

Lẹ́yìn tí ó parí iṣẹ́ pelu 7de laan ni ọdún 2015, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ fún eré ṣíṣe èyí tí Diane Venora gbé kalẹ̀ fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta ni ìlú California[6]. Leyin gbà tó padà sí South Áfríkà, ó gbà iṣẹ́ Vir die Voëls, ipa rẹ ninu ere yi lọ jẹ́ kí ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ níbi ayẹyẹ Tallgrass International Film Festival.[7] Ní ọdún 2017 ó bere ilé iṣẹ́ fún eré ṣíṣe tirẹ̀ tí ó pè ní Art of Acting South Africa.[8]

Ní ọdún 2018, ó sọ wípé ohun àti Andries Levi Pretorius fẹ́ ara wọn.[9] [10]Wọn ṣe ìgbéyàwó ni ọjọ́ kẹtà lélógún oṣù kejì, ọdún 2019.[11][12][13]

  1. Marisa, Fockema (1 November 2017). "Ons Vir die Voëls-aktrise se ster skitter al hoe helderder!". Netwerk24. https://www.netwerk24.com/huisgenoot/Nuus/ons-vir-die-voels-aktrise-se-ster-skitter-al-hoe-helderder-20171023. 
  2. "simone-nortmann-hou-die-talent-dop" (in Afrikaans). Rooi Rose. 23 April 2018. https://www.rooirose.co.za/simone-nortmann-hou-die-talent-dop/. 
  3. Madge, Booth (30 July 2015). "EKSKLUSIEF: Simoné Nortmann verlaat '7de Laan". Netwerk24. https://www.netwerk24.com/Sarie/Bekendes/Het-Jy-Gehoor/eksklusief-simone-nortmann-verlaat-7de-laan-20170914. 
  4. "Vir die Voëls se Simoné Nortmann maak silwerskerm debuut – Afrikaanse Films" (in Afrikaans). Afrikaansefilms. https://afrikaansefilms.com/nuus/vir-die-voels-se-simone-nortmann-maak-silwerskerm-debuut. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. "HONORIS CRUX". http://flecha.co.uk/honoris_crux.html. 
  6. Madge, Booth (18 August 2015). "Simoné Nortmann op pad na Hollywood!" (in Afrikaans). Netwerk24. https://www.netwerk24.com/Sarie/Bekendes/Het-Jy-Gehoor/simone-nortmann-op-pad-na-hollywood-20170914. 
  7. Johnson, Zach (19 October 2017). "Rose McGowan Cancels All Public Appearances in Wake of Harvey Weinstein Scandal". E!. https://www.eonline.com/news/888024/rose-mcgowan-cancels-all-public-appearances-in-wake-of-harvey-weinstein-scandal. 
  8. "Art of Acting South Africa". Stroomopfilm. 9 August 2018. http://www.stroomopfilm.co.za/en/cast/vivian. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "SIMONÉ NORTMANN IS VERLOOF" (in Afrikaans). Rooi Rose. 23 October 2018. https://www.rooirose.co.za/simone-nortmann-is-verloof/. 
  10. "She said yes! ‘7de Laan’ actress Simone Nortmann is engaged". All4women. 24 October 2018. https://www.all4women.co.za/1615312/entertainment/sa-celebs/she-said-yes-7de-laan-actress-simone-nortmann-is-engaged. 
  11. "PICS: Actress Simone Nortmann's dreamy wedding snaps". Channel24. 26 February 2019. https://www.channel24.co.za/The-Juice/News/pics-actress-simone-nortmanns-dreamy-wedding-snaps-20190226. 
  12. "Simoné Nortmann en rekenmeester trou". Maroelamedia. 2 February 2019. https://maroelamedia.co.za/vermaak/bekendes/simone-nortmann-en-rekenmeester-trou/. 
  13. "She said yes! ‘7de Laan’ actress Simone Nortmann is engaged". Eyethunews. 22 May 2019. Archived from the original on 2 June 2019. https://web.archive.org/web/20190602110137/https://eyethunews.co.za/all4women/494601/she-said-yes-7de-laan-actress-simone-nortmann-is-engaged/.