Simu Liu
Ìrísí
Simu Liu | |||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Liu ní ọdún 2019 | |||||||||||||||||||||
Orúkọ àbísọ | 刘思慕 | ||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹrin 1989 Harbin, Heilongjiang, China | ||||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Canadian[1] | ||||||||||||||||||||
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Western Ontario (HBA) | ||||||||||||||||||||
Iṣẹ́ |
| ||||||||||||||||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2012–present | ||||||||||||||||||||
Awards | Full list | ||||||||||||||||||||
|
Simu Liu ( /ˈsiːmuː ˈliːjuː/ SEE-moo-_-LEE-yoo;[2] Àdàkọ:Zh; tí a bí ní ọjọ́ kandínlógún oṣù Kerin ọdún 1989) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kanada. Ó gbajúmọ̀ fún kíkọ́ ipa Shang-Chi nínú fíìmù Marvel Cinematic Universe, Shang-Chi and the Legend of the Ten Rings tí ó jáde ní ọdún 2021. Ó tún kó ipa gẹ́gẹ́ bi Jung Kim nínú fíìmù CBC Television Kim's Convenience[3] ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ ACTRA Award àti Canadian Screen Awards fún ipa rẹ̀ nínú Blood and Water.[4]
Ní ọdún 2022, Liu ko ìwé We Were Dreamers,[5] Time sì pè é ní ará àwọn òṣèré ọgọ́rùn-ún tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní àgbáyé.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:Cite tweet
- ↑ Àdàkọ:Cite tweet
- ↑ "Kim's Convenience – CBC Media Centre". Canadian Broadcasting Corporation. Retrieved 29 July 2016.
- ↑ "Simu Liu – Academy.ca". Academy.ca. 8 January 2017. Retrieved 22 January 2017.
- ↑ "From immigrant to superhero: Simu Liu tells his own origin story in memoir 'We Were Dreamers'". www.wbur.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-21.
- ↑ "Simu Liu: The 100 Most Influential People of 2022" (in en). Time. 23 May 2022. https://time.com/collection/100-most-influential-people-2022/6177789/simu-liu/. Retrieved 2022-12-21.