Abubakar Tafawa Balewa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Sir Abubakar Tafawa Balewa)
Jump to navigation Jump to search
Abubakar Tafawa Balewa
Abubakar.jpg
Alakoso Agba ile Naijiria
In office
October 1, 1959 – January 15, 1966
Arọ́pòNone
Personal details
Ọjọ́ìbí1912
Bauchi, Nigeria
Aláìsí15 January, 1966
Ẹgbẹ́ olóṣèluNorthern People's Congress

Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) je omo orile ede Nàìjíríà, lati apa ariwa ile Naijiria. Balewa je Alakoso Agba (prime minister) akoko fun ile Naijiria ni Igba Oselu Akoko ile Nàìjíríà leyin igba ti Nàìjíríà gba ominira ni odun 1960. Eni ayesi ni kariaye, o gba owo ni orile Afrika gege bi ikan lara awon ti won daba idasile Akojoegbe Okan ara Afrika (Organization of African Unity, OAU).

Igba ewe ati ise-owo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]