Jump to content

Sirat al-Nabi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Siratun Nabi
Cover of Urdu Version
Olùkọ̀wéShibli Nomani
Àkọlé àkọ́kọ́سیرت النبی
TranslatorMuhiuddin Khan
CountryBritish India
LanguageUrdu
SubjectMuhammad
GenreBiography
PublisherDarul Musannefin Shibli Academy
Publication date
1918–1955
Media typeHardcover
OCLC10695489
297.09

Siratun Nabi (Urdu: سیرت النبی) jẹ́ ìwé seerah alábala méje, tàbí ìwé ìtàn ìgbésí-ayé òjíṣẹ́ ẹ̀sìn Islam, Muhammad, èyí tí Shibli Nomani àti Sulaiman Nadvi kọ. Èyí jẹ́ iṣẹ́ Shibli Nomani tí ọjọ́ rẹ̀ kò ì pẹ́ púpọ̀, tí ó sì gbajúmọ̀ jù lọ.[1][2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]