Jump to content

Siyar A'lam al-Nubala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Siyar A'lam al-Nubala'
Olùkọ̀wéAl-Dhahabi
Àkọlé àkọ́kọ́سير أعلام النبلاء
CountryMamluk Sultanate
LanguageArabic
SubjectBiographical dictionary
GenreBiography
Published14th century
Media typeManuscript
Pages28 volumes

Siyar A‘lām al-Nubalā’ (Lárúbáwá: سير أعلام النبلاء‎) jẹ́ ìwé atúmọ̀ èdè ajẹmọ́ ìgbésí-ayé ẹ̀dá, èyí tí al-Dhahabi kọ tó ní ṣe pẹ̀lú ìtàn ìgbésí-ayé àwọn Mùsùlùmí lásìkò al-Dhahabi.[1] Ìpín méjì àkọ́kọ́ ti ìwé Siyar oní ìpín mẹ́rìnlá yìí dá lórí ayé Muhammad àti Rashidun, èyí tí wọ́n yọ lára Tarikh ti al-Dhahabi.[2] Al-Dhahabi pín ìwé náà sí abala ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìran tí oníkálùkú wọn gbé.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "نبذة عن كتاب سير أعلام النبلاء". موضوع (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2023-04-04. 
  2. Marouf, Bashar Awwad (1996). "Editor's Introduction". In Arna’ūt, Shu‘ayb (in ar). Siyar A‘lām al-Nubalā’ (11th ed.). Beirut: Resalah Publishers. pp. 93–94. 
  3. "الذهبي ومنهجه في سير أعلام النبلاء - بشار عواد معروف". ar.islamway.net (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2023-04-04.