Jump to content

Skales

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Skales
Sakles performing "Shaku Shaku" at the 24th edition of the Koroga Festival in December 2018
Sakles performing "Shaku Shaku" at the 24th edition of the Koroga Festival in December 2018
Background information
Orúkọ àbísọRaoul John Njeng-Njeng
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹrin 1991 (1991-04-01) (ọmọ ọdún 33)
Kaduna State, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Rapper
  • singer
  • songwriter
InstrumentsVocals
Years active2000–present[1]
Labels
Associated acts

Raoul John Njeng-Njeng (tí a bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹrin, ọdún 1991) tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Skales (tí àpèja rẹ̀ ni Seek Knowledge Acquire Large Entrepreneurial Skills), jẹ́ olórin tàkasúféé àti akọrin kalè tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2000, ó bèrè sí ní ṣe àkọsílẹ̀ orin tàkasúféé ni ilu Kaduna, Nàìjíríà . Larin odun 2007 ati 2008, ó rin ìrìn àjò lọ sí ilu Jos láti sise pẹ̀lú Jesse Jagz àti Jeremiah Gyang. In 2008, ó kopa ninu ìdíje gbogbogbọ̀ tí àríwá Zain ó sì borí idije ọ̀hún. Àwọn èèyàn ṣe ìtẹ́wọ́gbà orin adákọ rẹ̀ "Must Shine" ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Jos àti Abuja.[2] Ó padà kó lọ sí Èkó láti máa ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Empire Mates Entertainment (E.M.E) ní ọdún 2009.[3]

Skales ti kọrin pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbajúgbajà akọrin bíi Akon, eLDee, tekno, Harmonize, Jeremiah Gyang, Banky W àti Knighthouse. Orin rẹ̀ tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ ni "Shake Body", "Mukulu", "Keresimesi", "Komole", "My Baby", "Take Care of Me" ati "Denge Pose". Lẹ́yìn tó dẹ́kun máa ṣiṣẹ́ pẹ̀lú E.M.E ní oṣù karùn-ún ọdún 2014, ó dá ilé-iṣẹ́ agbórinjáde tirẹ̀ kalẹ̀ tí ó sọ ní OHK Music record label. Ọdún 2015 ni ó gbé álíbọ́ọ̀mù rẹ̀ jáde tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Man of the Year was released.[4]

  1. "Singer Skales Floats Record Label". P.M. News. 8 May 2014. Retrieved 29 July 2014. 
  2. "Skales Biography "Raoul John Njeng-Njeng" (Nigerian Music Artist)". Nigerianmusicnetwork. Archived from the original on 27 September 2020. Retrieved 13 November 2013. 
  3. "Skale's Biography & Updated profile – Latest Albums & Songs of Skales – Recent Pictures & Videos of Skale". Pulse. 11 March 2014. Retrieved 31 July 2014. 
  4. Akan, Joey (20 February 2015). "Singer soon to release album, 'Man of the year'". Pulse. Retrieved 5 March 2015.