Wizkid (musician)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ayodeji Ibrahim Balogun ( ti abi ni 16 July 1990),[1] lori ere itage ama n pe ni Wizkid, o je̩ olukọrin ti owa lati ilu Naijiria. Lati ọmọ ọdun mọkanla ni oti bẹrẹ sini kọrin, otun ṣe record pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ Glorious Five, ẹgbẹ ti ohun ati awọn ọrẹ rẹ dasilẹ. Ni ọdun 2009, arakunrin [[Banky W]] gba wizkid si inu ẹgbẹ akọrin rẹ, eyi tin jẹ [[ Empire Mates Entertainment]] (E.M.E). Ni ọdun 2010 , wizkid di gbajumọ aye pẹlu orin rẹ "[[Holla at Your Boy]]" lati ẹrọ orin rẹ "[[Superstar]]" ti ojade ni 2011.Ẹrọ orin ẹkeji ti wizkid gbejade ni ọdun 2014 ni awọn orin bi "Show You the Money" , "[[Jaiye Jaiye]]"ati bẹbẹlọ

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help)