Wizkid

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ayodeji Ibrahim Balogun (ojoibi 16 July 1990), lori ere itage ama n pe ni Wizkid, o je̩ olukọrin ti owa lati ilu Naijiria. Lati ọmọ ọdun mọkanla ni oti bẹrẹ sini kọrin, otun ṣe record pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ Glorious Five, ẹgbẹ ti ohun ati awọn ọrẹ rẹ dasilẹ. Ni ọdun 2009, arakunrin Banky W gba wizkid si inu ẹgbẹ akọrin rẹ, eyi tin jẹ Empire Mates Entertainment (E.M.E). Ni ọdun 2010 , wizkid di gbajumọ aye pẹlu orin rẹ Holla at Your Boy lati ẹrọ orin rẹ Superstarti ojade ni 2011.Ẹrọ orin ẹkeji ti wizkid gbejade ni ọdun 2014 ni awọn orin bi "Show You the Money" ,Jaiye Jaiye ati bẹbẹlọ[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Muziek voor iedereen.". Muziek voor iedereen - Spotify (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). Retrieved 2020-04-25. 
  2. "Wizkid Archives". Pan African Music. Retrieved 2020-04-25.