Olamide

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Olamide
Orúkọ àbísọOlamide Adedeji
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kẹta 1989 (1989-03-15) (ọmọ ọdún 31)
Bariga, Lagos State, Nigeria
Irú orinHip hop
Occupation(s)
InstrumentsVocals
Years active2011–present
LabelsYBNL Nation
Associated acts

Olamide Adedeji tí a bí ní ọjọ́ Kéẹ̀dógún oṣù Kẹta,ọdún 1989 (15-3-1989), ní agbègbè Bàrígà ní ìpínlẹ̀ Èkó tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọlámidé Badoo tàbí BaddoSneh, jẹ́ gbajú gbajà olórin hip-hop, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2] Ó jẹ́ olórin hip-hop tí ó ń akọrin pẹ̀lú àmúlù-ma la èdè Yorùbá àti èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́gẹ́ bí akọrin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọlámidé gbé orin tí anọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ' Ẹni Dúró' jáde lábẹ́ Ilé-iṣẹ́ agbórin jáde Coded Tunes lábẹ́ àkóso ID Cabasa. Orin náà lò gbe Ọlámidé sí ipò gíga láàrín àwọn olórin Hip-hop lóríẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Olamide performing at the first edition of his OLIC concert.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. liano (2019-09-01). "Olamide's New Song "Pawon" is a party starter". 9jabaz. Retrieved 2019-09-01. 
  2. "Olamide's Biography". Biography Home: Olamide Personal Data. Retrieved 8 January 2014.