Fireboy DML
Ìrísí
Fireboy DML | |
---|---|
Fireboy DML in 2019 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Adedamola Oyinlola Adefolahan[1] |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kejì 1996 Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Irú orin | Afrobeats, R&B |
Occupation(s) |
|
Years active | 2012–present |
Labels | YBNL Nation, Empire Distribution |
Associated acts | |
Website | fireboydml.com |
Adedamola Oyinlola Adefolahan (tí wọ́n bí ní 5 February 1996),[2] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Fireboy DML, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ YBNL Nation, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tí Olamide dá sílẹ̀.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "AFAR". ASCAP. American Society of Composers, Authors and Publishers. Retrieved July 10, 2023.
- ↑ "Watch Fireboy DML's New Music Video for 'Need You'". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 January 2020. Retrieved 17 January 2020.
The 23-year-old artist...
- ↑ "Fireboy DML album make pipo do wow!". BBC News Pidgin. 29 November 2019. https://www.bbc.com/pidgin/tori-50597826.