Sofia Assefa
Ìrísí
Assefa at the 2010 Memorial van Damme | ||||||||||||||||||||||||||||||||||
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kọkànlá 1987 Addis Ababa, Ethiopia | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Height | 1.67 m (5 ft 51⁄2 in) | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Weight | 52 | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Sport | ||||||||||||||||||||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Track and field | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Event(s) | 3000 metres steeplechase | |||||||||||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Sofia Assefa ni a bini ọjọ kẹrinla, óṣu November, ọdun 1987 si Ilu Tenta, South Wollo jẹ elere sisa ti ọna jinjin to dalori steeplechase ti metres ẹgbẹrun mẹta. Sofia gba ami idẹ ọla ti silver ni summer olympics ti ọdun 2012[1][2].
Àṣèyọ̀ri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sofia kopa ninu idije ilẹ afirica nibi to ti pari pẹlu ipo kẹrin ni ọdun 2008. Ni ọdun 2019, Sofia pari pẹlu ipo kẹtala ninu idije agbaye[3]. Ni ọdun 2012, Sofia gba ami ẹyẹ ọla ti silver ninu summer olympic ti steeplechase ti ẹgbẹrun mẹta Metre[4]. Ni ọdun 2013, Sofia gba ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ninu idije agbaye to aaye ni Moscow[5][6]. Ni ọdun 2015, Sofia gba ami ẹyẹ ti ọla ti gold ni ere ilẹ afirica to waye ni Brazzaville.