Jump to content

Sophia Mwasikili

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Sophia Mwasikili
Personal information
OrúkọSophia Edward Mwasikili
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kẹrin osù Kẹrin ọdún 1986
Playing positionOlùgbèjà
National team
Tanzania
† Appearances (Goals).

Sophia Edward Mwasikili tí a bí ní ọjọ́ kẹrin osù Kẹrin ọdún 1986 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò olùgbèjà lórí pápá àti asáájú fún ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Tanzania .

Mwasikili ti sojú orílẹ̀-ède Tanzania ní ìpele àgbà ní bi ìdíje <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/2018_Africa_Women_Cup_of_Nations_qualification" rel="mw:ExtLink" title="2018 Africa Women Cup of Nations qualification" class="mw-redirect cx-link" data-linkid="43">Africa Women Cup of Nations qualification</a>ti ọdún 2018 .

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]