St. Thomas Anglican Primary School, Badagry
Ìrísí
St. Thomas Anglican Primary School jẹ́ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ tí wọ́n dá sílẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nigeria lọ́dún 1845 ní ìlú Badagry, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Àlùfáà Rev. Golmer tí ìjọ Church Missionary Society (CMS) ni ó dá ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ St Thomas Anglican sílẹ̀ lọ́dún 1845. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé náà ni ibí tí ilé alájà àkọ́kọ́ wà ní Badagry. Ọ̀gbẹ́ni Philips ni olùkọ́ àti olùkọ́-àgbà àkọ́kọ́ ní ilé-ìwé náà láti ọdún 1845 sí 1867.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "ST THOMAS PRIMARY SCHOOL, Badagry - Lagos Schools Online". Archived from the original on 2023-01-21. Retrieved 2023-01-21. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)