Stellah Nantumbwe
Stellah Nantumbwe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Stella Nantumbwe 1991 (ọmọ ọdún 32–33) |
Orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Greenwich (Bachelor of Science in Business Computing) |
Iṣẹ́ | Beauty Pageant Contestant, Pageant Coach & Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2013–present |
Gbajúmọ̀ fún | Miss Uganda & Big Brother Africa |
Stella Nantumbwe jẹ́ òṣèré àti omidan Uganda ní ọdún 2013.[1] Òun ni aṣojú Uganda ní Big Brother Africa ní ọdún 2014.[2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Stella sí ìdílé Angela Nakiyonga àti Rogers Nsereko ní ọdún 1991 ní orílẹ̀ èdè Uganda. Òun ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ bí. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Buganda Road Primary School àti Kabojja International Secondary School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Greenwich níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Business Computing ní ọdún 2012.[4][5]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2013, nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìlélógún, ó lọ fún ìdíje omidan Uganda, ó sì gbé igbá orókè nínú ìdíje náà.[6] Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 2014, ó gboyè omidan tó gbajúmọ̀ jù lórílẹ̀-èdè Uganda.[7][8] Ní oṣù kẹsàn-án, ọdún 2013, ó ṣe aṣojú fún Uganda níbi ìdíje omidan àgbáyé.[9][10] Ó kópa níbi ìdíje Big Brother Africa ní ọdún 2014 gẹ́gẹ́ bí aṣojú fún Uganda.[11][12] Ellah ti kópa nínú eré fíìmù, ó sì ti ṣe atọ́kun ètò lórí tẹlẹfíṣọ̀nù. Ó ko ipa Isabella Arroyo nínú eré El Cuerpo del Deseo ní ọdún 2016.[13] Ní ọdún 2017, ó kópa nínú eré Bella[14][15][16]. Ní ọdún 2018, ó ṣe atọ́kun ètò Scoop on Scoop lóri Urban TV. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn adájọ́ fún ìdíje omidan Uganda ní ọdún 2018.[17] Òun ni igbá kejì Ààrẹ fún Africa Music Industry Awards.[18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Batte, Edgar (15 July 2013). "Stellah Nantumbwe is Miss Uganda". Daily Monitor. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Odeke, Steven (9 December 2014). "Time to look for a job - Ellah". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Irene Namarah (2 November 2016). "Sophisticated and bitchy Stella Nantumbwe". Matooke Republic. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Kalema, Lawrence (12 March 2018). "Former Miss Uganda, Stella Nantumbwe Dumps Boyfriend". Kampala: UgandanBuzz.Com. Retrieved 14 August 2018.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ghafla.com (20 February 2018). "Star Struck Tuesday: Stella Nantubwe To Feature In Nigerian Film". Kampala: Ghafla.com. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Odeke, Steven (26 May 2013). "Nantumbwe Wins Miss Uganda 2013 Central Region". New Vision. Kampala. Retrieved 11 August 2018.
- ↑ Baligema, Isaac (14 July 2013). "Stella Nantumbwe crowned Miss Uganda 2013". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Eupal, Felix (14 July 2013). "Stella Nantumbwe is Miss Uganda 2013". The Observer (Uganda). Kampala. Archived from the original on 11 December 2018. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Edgar R. Batte (11 September 2013). "Miss Uganda Optimistic About Taking World Crown". Daily Monitor. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ BellaNaija.com (2 October 2013). "Glamorous Belles! See What Our African Queens Wore at the Miss World 2013 Finale in Bali, Indonesia". Lagos: BellaNaija.com. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Businge Brian Franco (December 2014). "Stella Nantumbwe Finally Evicted From The House – BBA Hotshots". Kampala: Howwe.Biz. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Carol Natukunda, and Halima Nampiima (22 December 2014). "Ellah: I had plans to marry BBA's Idris". New Vision. Kampala. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Namarah, Irene (31 October 2016). "Will Ellah nail Isabel’s character in Uganda’s Second Chance?". Kampala: Matooke Republic. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Big Eye (2 July 2018). "Stella Nantumbwe Lands Nollywood Movie Role". Kampala: Big Eye Uganda. https://bigeye.ug/stella-nantumbwe-lands-nollywood-movie-role/.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Isaac (5 August 2015). "Stella Nantumbwe 'Ellah' Gets A New Programme On Urban TV". Kampala: Chano8.Com. Archived from the original on 23 February 2020. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Ssempijja, Reagan (23 October 2017). "Matt Bish Films premieres star-packed movie Bella". New Vision. Kampala: New Vision Publications. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Ahumuza, Allan (24 July 2018). "Former Miss Uganda Contestant Attacks Pageant Judges". Kampala: Chano8.Com. Archived from the original on 16 January 2020. Retrieved 14 August 2018.
- ↑ Josh Ruby (February 2018). "Stella Nantumbwe Ellah To Host African Music Industry Awards". Kampala: Mbu Uganda. https://mbu.ug/2018/02/28/stella-nantumbwe-ellah-host-african-music-industry-awards/.