Steve Ayorinde
Ìrísí
Steve Ayorinde | |
---|---|
Former Lagos State Commissioner for Information & Stretegy; Tourism, Arts & Culture | |
In office October 2015 – May 2019 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Keje 1970 Ibadan, Oyo State Nigeria |
Alma mater | Obafemi Awolowo University, University of Lagos, University of Leicester |
Profession | Journalist / Media Consultant |
Steve Olúṣẹ̀yí Ayọ̀rìndé /θj/ (tí wọ́n bí lọ́dún 1970) jẹ́ kọmíṣọ́nnà-àná fún ètò ìrìn-afẹ́, iṣẹ́-ọ̀nà àti àṣà tí Ìpínlẹ̀-Èkó lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ṣáájú àkókò yìí, ó jẹ́ kọmíṣọ́nnà nípa ìròyìn àti ọgbọ́n-ọnnú nígbà ìṣèjọba gómìnà-àná tí Ìpínlẹ̀ náà, Akinwunmi Ambode lọ́dún 2015,[3][4][5] Bákan náà, ó ti fìgbà kan jẹ́ Ọ̀gá-àgbà tí ilé-isé ìwé-ìròyìn National Mirror, àti olóòtú ìwé-ìròyìn The Punch[6] ní Nàìjíríà.[7]
Bákan náà, Ayorinde jẹ́ ọ̀kan lára gbajúmọ̀ lámèyító nípa sinimá àti iṣẹ́-ọ̀nà, ti ó sì tún ti jẹ́ adájọ́-aláṣàyàn fún àmì-ẹ̀yẹ àgbáyé bíi Toronto International Film Festival, Cannes Film Festival, Berlin International Film Festival, AMAA àti Mumbai International Film Festival.[8]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The Face Of Tourism In Lagos Will Change This Year By Seye Kehinde". The Lagos Daily News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-07. Archived from the original on 2020-08-15. Retrieved 2020-05-24.
- ↑ "MR. STEVE AYORINDE – HON. COMMISSIONER". Tourism, Arts & Culture - Lagos State Government (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-24.
- ↑ Chika Ebuzor (12 November 2015). "Steve Ayorinde: Commissioner criticises media for culling The Economist's article on Ambode".
- ↑ "Bamigbetan is Lagos’ New Information Commissioner!". Gidi News. 11 January 2018. Archived from the original on 6 September 2018. Retrieved 25 March 2023.
- ↑ "Ambode swears in 23 commissioners". Vanguard News. 19 October 2015.
- ↑ "Steve Ayorinde".
- ↑ "Footprint of David | Advisory Board" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-24.
- ↑ "Steve Ayorinde". African Film Festival Inc.