Struthionidae

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Struthio camelus

Struthionidae jẹ́ ẹbí àwọn ẹyẹ tí kò ní ìyẹ́ tí ó kọ́kọ́ fara hàn ní ìgbà Eocene. Ìdílé Struthio, ní aṣojú rẹ̀ lóní ṣùgbọ́n ó tún ní àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé míràn.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mayr, G. (2009).