Jump to content

Sulliman Mazadou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sulliman Johan Mazadou (ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu Kẹrin ni ọdun 1985 ni Marignane, France ) jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede Niger ti o nṣere fun ẹgbẹ agbabọọlu Faranse US Marignane ni Championnat de France amateur . O jẹ ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede Niger ti o gba ni 2012 Africa Cup of Nations pelu Gabon [1] ati ọkan ninu awọn agbabọọlu Niger ni ifẹsẹwonse lẹẹkansi Tunisia . [2]