Surita Febbraio

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Surita Febbraio tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀nOṣù kejìlá ọdún 1973 jẹ́ olùsáré oní fífò ti orílẹ̀ èdè South Africa .

Ó gba áámì-ẹ̀ye fàdákà All-AfricaGames ti ọdún 1999 níJohannesburg, tí ó sì pari pẹ̀lú ipò kẹjọ ní World Championships ti ọdún 2003 ní Paris, ó gba ààmìẹ̀yẹ African Championships ti ọdún 2004 ní Brazzaville ó sì parí pẹ̀lú ipò kẹjọ níbi World Athletics Final ti ọdún 2005 ní Monaco.

Àkókò tí ó kópa dára jùlọ jẹ́ àáyá 54.05, tí ó wáyé ní Oṣù Kẹrin ọdún 2003 níPretoria .

Ní ọdún 2006 Febbraio jẹ̀bi gbígbé testosterone . Àyẹ̀wò náà tí ó kún fún èròjà tí a fi òfin dè ni wón fi jíṣẹ́ ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣu kejìlá ọdún 2005 níbi àyẹ̀wò tí kò sí fún ìdíje ní orílẹ̀ ède South Africa. Ó ní ìdádúró ti IAAF láti Oṣù Kẹta Ọdún 2006 sí Oṣù kẹta Ọdún 2008. [1]

Àwọn Ààmìn Ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2003 – University of Pretoria Arábìnrin eléré ìdárayá ti ọdún náà[2]

Wo eléyìí náà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Àtòkọ ti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ eré ìdárayá tí kò hàn sí gbangba

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Doping Rule Violation". IAAF. 25 August 2006. http://www.iaaf.org/news/Kind=1073741824/newsId=35969.html. Retrieved 2006-12-28. 
  2. web.up.ac.za/default.asp?ipkCategoryID=11036

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]